Friday Oct 31 2014, 10:23
9837687
Irinisi ni isoni lojo
View
Audio
Comments
3311564
Gbon-gbon kan ko si, afi eni ti o ba n ti ara re
View
Audio
Comments
6456137
A kii gbo kiku ojo, ka da omi inu agbada nu
View
Audio
Comments
1253757
Anumo kan kii nu ile
View
Audio
Comments
1963718
Bi eye ba se fo ni a se n so oko re
View
Audio
Comments
3987978
Ajumobi ko kan ti aanu, eni ori ba da ni mo nii se ni ni oore
View
Audio
Comments